Smiley face

Ayefele Ranti Igba To N Fi Ese Mejeeji Rin Pelu Ope Si Oluwa: "Sibesibe Oluwa Dara Simi"

Awon Yoruba ni ti eru ba monu ro dandan ni ko mope du fun Oluwa oba. Eda ti ko tii ku ireti si wa fun-un laye. Ko si ipokipo ti eda le wa laye ki aye ope ma yo sile fun-un. Eniyan to ku ni tie tan patapatapa

Yinka Ayefele lo se afihan aworan oke yii pelu akole to so wi pe, "Sibesibe Oluwa Dara Simi" lori ero ayelukara.

E je ka wo die ninu awon iriwisi ti awon ololufe ati ore re fi dalohun nipa emi imoore re si Oluwa Oba:

Khadijah AtinukeAde Alabi:
I believe u have more people who love u now than even before. U r more famous, richer, and of course the talent. Thanks to God for everything.


Shinor Alegbeleye:
You are blossoming brother, I do not see you missing anything, I always thank God for your life, one in a billion rare breed human being; all thanks
to Almighty God.


Joke Johnson:
God can still do the unimaginable. Just believe.


Toyin Ajayi:
Touching tho,The Lord is ur strength and his blessings are endless on u,it is well with your soul,he will strengthen those bones IJN.


Yemisi Paragonbaby Awe:
I have the hope and believe Layinka. All of us will testify to ur miracle


Femi Oorun Solar:
Oluwaseun.... thats just ur word wen u look back. MON

Ogunlade Adekunle Joel:
He never sleeps and never too late, just keep the hope burning. IT'S WELL!


Micky Adegoke:
Many died with their two legs buried with their talents but God keeps you alive to pure out all your potentials so that when the time comes you will go
back empty and fulfilled (Dr Myles Monroe)


Fiezta Fiesta:
it's well egbon.. o ye olorun


Hajjia Shakirat BelloBature:
Joel it is well Insha Allah


Bukky Ladapo-Molade:
Beni!!! Oluwa Dara!!! One thing is for sure! He is a God of Possibilities!!!!!!


Hoghunjhobi Khehinde Vivian:
if God is still on the throne, u'll rise again


Winston Oladapo:
God has not forgotten you........He will surely do it for you.


Gani Kayode Balogun Jr:
It's well...

Pupo ninu awon ololufe Yinka Ayefele ni won si nigbagbo wi pe Yinka Ayefele si maa rin lojo kan pelu ese re. Awon kan si n fi oro itunnu mu lokan le wi pe o ti waye to dara bi ko tile lese. Ninu alaye won, ipa ti eda ko laye lo se koko ju lo. Nitori awon nnkan wonyii ni aye yoo maa ranti titi lai.

Gege bi oro awon ologbon aye, ojo ti won sin eda eniyan gan-an ko loku bikose ojo ti eda eniyan so ireti nu ninu igbe aye re. Oro Olorun so wi pe igbagbo ni orisun ati opin ohun gbogbo laye. Igbagbo nikan ni yoo si bori aye ati ohun gbogbo.

Ojo kan, Olayinka Ayefele ma fi ese rin, okiki yoo si kan kari gbogbo aye. Amin, Amin ati Amin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment