Labe ofin, awon gomina ti won ba ti gbese kuro lori aga isejoba ni eto si awon ajemonu kan gege bi gomina nigba kan ri.
Sugbon Kayode Fayemi gbese le gbogbo eto yii nikete ti ile ejo ro Segun Oni loye gege bi gomina Ipinle naa ti won si fi Omowe Kayode Fayemi ropo re ni kiakia gege bi olubori.
Bakan naa, ti e ko ba gbagbe, egbe PDP ni Segun Oni wa tele. Sugbon saaju eto idibo to gbe Oga Nla wole ni Segun Oni ti bo sinu egbe APC lati se atileyin fun Kayode Fayemi.
Ana ojo Isegun je ojo nla, emi Olorun ba Peteru Ayodele omo Fayose, eni ti a bi ni ojo ketala osu kokanla odun 1960 soro, o si tele ohun gbogbo ti oba oke wi fun-un.
Akoroyin fun Ayo Fayose, Ogbeni Idowu Adelusi si fonrere iroyin ayo naa si gbogbo aye:
"Governor Ayo Fayose is restoring all the privileges of former Governor Segun Oni. His portrait, which was removed from the Governor's Office by former Governor Kayode Fayemi, has been returned."All those who served with him and whose portraits were removed by the past administration such as former chief press secretaries, among others, have been returned."It was the Fayemi's administration that even stopped their financial entitlements when it made the House of Assembly to pass a bill that Oni and Fayose were not due for such."The excuse they gave was that Fayose did not complete his tenure and Oni's tenure was unknown to law because the court removed him from office."The Fayose's administration appreciates the contributions of those who have led the state in the past and would not in any way rubbish such."We are ready to acknowledge all and would not as a result of political differences rubbish what people have done in the past," Ogbeni Idowu Adelusi
0 comments:
Post a Comment