Smiley face

E Maa Fi Adura Ran Jonathan Lowo, Ota Ti Poju Enimi Lo. Talo So Bee?

Gomina Ipinle Bayelsa, Seriake Dickson lo so lana ode yii nibi isin idupe to waye ni gbongan asa Gabriel
Okara to wa ni Yenagoa to je olu ilu Ipinle naa wi pe Aare Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan, GCFR, BNER, GCON niilo adura gidigidi fun aseyori ise takuntakun to n se lowo.

Gomina tun tenu mo wi pe orileede Nigeria niidi adura lowolowo bayii latari sunmomi ati ote ti awon eniyan ibi fi n yo alaafia Naija lenu.

"I wish to urge all Nigerians to pray for the peace, unity and stability of the country. This is the time to reunite our country through prayers.

Now that the 2015 general elections are approaching, people should shun
do or die politics.

Those seeking political offices should know that power comes from God."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment