Smiley face

Se Ki Won Pa Ni Abi Ki Won Fi Sewon Gbere: Maanu To Pa Omo Odun Mokanla Leyin To Ba Sun Tan?

Ogbeni ti oruko re n je Charles Warner lati Ipinle Oklahoma to wa ni Ilu Amerika lo ba Adrianna Waller, omo odun mokanla to je omo orebirin re ti oruko re n je Shonda Waller lajosepo tipatipa, leyin eyi lo tun seku pa omodebirin naa.



Odun 1997 ni isele buruku naa sele, sugbon igbejo naa si wa ni ile ejo di oni. O si dabi eni wi pe won ti fe dajo iku fun okunrin naa ba yii.

Sugbon orebirin okunrin yii, to je iya omo ti won seku pa ko fe ki won pa ololufe re rara. E gbo ohun ti Shonda Waller wi:

'If they truly want to honor me, then they will do away with the death penalty for him, and they will give him life in prison without the possibility of parole, because that's the only thing that's gonna honor me.'

'I can only see him spending the rest of his life in prison and dying in prison, without him ever walking out of those cell walls.'

Osu Januari odun to n bo ni atejade awon onigbejo fi ye wa wi pe won yoo yanju 'Papa Tosibe' patapata.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment