Adari ijo irapada agbaye, Oluso-Aguntan E. A Adeboye se abewo si Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose ninu ile re to wa ni Ado Ekiti lojo odun.
Igba to ya ni wooli olokiki agbaye naa bere adura pelu oruko Jesu, Fayose kunle lori orunkun re mejeeji nigba ti oun ati awon isomogbe re si bere si ni i se amin kikankikan.
Pastor W.F. Kumuyi ti ijo Deeper Life naa wa lara awon ti won se abewo si Fayose.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment