Smiley face

Bi Awon Eniyan Se Sinu Lana Ni YII Kaakiri Agbaye

Asiko awe je akoko ti awon musulumi ododo maa n wa ju Oluwa fun aanu ati idarijin ese. O tun je akoko ibukun ati Alaada fun awon olusin Oba Mimo. Adura wa ni wi pe gbogbo ebe adura wa pata ni Oba Allah yoo tewogba lowo wa. Gbogbo ohun taa n beere ni rere ni Olurun yoo fi le wa lowo. Emi wa yoo si sika awe naa ni agbara Oluwa.
 Bi awon eniyan se sinu lana ni yii kaakiri agbaye
Awon Foto oke yii wa lati China, USA, Holland, Saudi Arabia, The Gambia, Japan, United Kingdom, Morocco, Sudan ati bee bee loo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment