Smiley face

Buhari Fe Din Awon Minisita Nigeria Si Mokandilogun (19) Lati Mejilelogoji (42) To Wa Tele

Yoruba bo, won ni oba mewa igba mewa loni ile aye. Bayii ni i se nnkan mi ko si yi pade. Ninu iroyin tuntun to jade lonii, ohun ti a gbo ni wi pe Aare Muhammadu Buhari ti pinnu wi pe minisita oun ko ni ju mokandinlogun lo (19) yato si mejilelogoji (42) ti a ti n ni tele. Eyi wa lara ero re lati din owo ijoba nina ku. A tun gbo wi pe PMB yoo le ajo EFCC ati ICPC papo si eyo kan soso. Iroyin yii lo lu sita lonii, eyi si mu da wa loju wi pe aare ko ni pe kede awon minisita ti won yoo ba sise papo ninu isejoba re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment