Awon onise ibi kan ti lo kan iyaloja gbogboogbo ti ilu Ijebu ode, Alhaja Sadia
Elewuju, mo inu ile re lana (8-7-15) ni nnkan bi ago meta osan ti won si fi ada sa iya eni odun mejilelogorin (82) sakasaka.
Nibayii, enikeni ko le so pato nipa ibi ti iku iya naa ti wa.
#Nnkan Mbe
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment