Amofin Dele ni won seku pa lojo kerinla osu kefa odun 2015 ni osan ojo Isinmi ninu ile re.
Iyawo okunrin naa ba gbe ero gaasimileti lati pe awon olopa latari isele to waye lojo naa.
Oga olopa olotelemuye ti oruko re n je Lapade lo sare debi isele naa. Kete to debe lo bere si ni fi oro wa awon eniyan to wa layika lenu wo lati mo taani amokunseka to pa Amofin Dele.
Ibeere ti Lapade n beere lowo awon eniyan naa ni yii.
Lapade: Ibo lo wa nigba ti won seku pa Amofin Dele?
Iyawo Amofin Dele: Mo wa loke, mo n sun nigba ti won seku pa oko mi.
Alase (eni ti n ba won se ounje): Yara idana ni mo wa ti mo n se iresi joloofu olororo.
Omoodo: Emi lo ko awon omo pada wa sile lati ile iwe won to wa ni Bariga.
Baba Ologba: Ewe ododo, fulawa, ni mo n ge leyinkule nigba ti isele naa waye.
Asobode: Oga mi ran mi lo ra iwe iroyin Alaroye lorita nigba naa ni o.
Ologbon ni Lapade, o ti pe ninu ise olotelemuye. Igba to gbo esi onikaluku, o mo odaran to se ise ibi naa lai beere ibeere kankan siwaju mo. Oju-ese naa lo si mu odaran naa lo si tesan.
Taani odaran ti Lapade mu lo si tesan???

0 comments:
Post a Comment