Awon Yoruba ni ko si ohun tuntun labe orun mo. Sibesibe, awon isele kayeefi ko ye maa waye. Bi ko tile je tuntun, sibesibe iyanu lo jo loju tiwa.
Arakunrin Dapo Adaralegbe to je omo ile Nigeria ti pegede nipa yiyi iseda re kuro ni t'okunrin to wa tele si t'obirin.
Ile iwe Ifafiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile Ife ni omokunrin naa lo ki won to le kuro ni ile iwe naa lodun 2001 latari esun ibalopo okunrin si okunrin.
Leyin igba naa lo ni anfaani lati wo ilu Netherland nibi ti won ti ba se asepari ise oge abo sii lara.
Ogbeni Dapo Adaralegbe ko sai dara legbe nikan, ko da, o gbe ounje fegbe o tun gbawo bo ninu akitiyan re pata.
Nibayii, Ogbeni Dapo Adaralegbe ti yii oruko re pada si Arabirin Stephanie Rose.
Arabirin Stephanie Rose si n wa ololufe tooto, okunrin to se e fokan tan ti yoo maa se ade ori fun-un ati ojuse oko ninu ile.

0 comments:
Post a Comment