Ohun Meji Ti E Ko Mo Nipa Eye Ogongo (Ostrich) Niyi Olayemi Oniroyin 7/25/2015 07:23:00 pm Ọ̀rọ̀ Olóòtú Edit Bi o tile je wi pe gbogbo eniyan lo mo wi pe Ogongo loba eye, kinihun si loba eranko, n je eyin tun mo eleyii nipa eye ogongo (Ostrich) bi...? Eye Ogongo le sare ju eshin lo. Bakan naa, ako (male) Ogongo le bu ramuramu bi Kinihun ololaaju. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Sàràkí lè dá Buhari lágbo nuÌkà tí ẹbi Abiola ṣe fún MKO ju ti ...Ìgbà èwe: Mo pàdánù ọrẹ méjì tí mo ... Ohun Meji Ti E Ko Mo Nipa Eye Ogongo (Ostrich) Niyi Reviewed by Olayemi Oniroyin on 7/25/2015 07:23:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment