A o wa Ogede agbagba to po die, a o bo eepo ara re kuro.
Leyin eyi ni a o ge wewe sinu abo nla kan pelu omi to po die ninu.
A o re fun ojo meta...
Lilo: A o maa mu ife kan (one glass cup) laaro, losan ati lale.
Ogbe inu naa yoo di ohun igbagbe.
Akiyesi Pataki:
Ki eni na ma se je awon ounje ti won din. Ki eni naa ri pe oun je ounje ki o to di wi pe ebi bere si ni i pa.
0 comments:
Post a Comment