Oni ojo kokanlelogun, osu kejo (Aug 21), odun 2015 ni Gomina Abiola
Ajimobi n se igbeyawo fun omo re obirin, Ajibola pelu oko omo re,
Ayokunle Olayiwola.
Orisirisi awon eniyan nlanla ati awon gomina lati apa iwo-oorun guusu Naijeria ni won ti pejupese sibe. Omo Baba Olowo, Davido ati Olamide ko si dake orin lati maa fi da awon eniyan lara ya.
Afikun iroyin si n bo laipe...

0 comments:
Post a Comment