Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je.
Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo to wa niluu Eko lagbo wi pe o bere ise fiimu agbelewo lodun 2006.
Omo bibi ilu Edo ni sugbon ede Yoruba eni re da saka.

0 comments:
Post a Comment