Awon Eegun kan ni owo awon olopa ti te leyin ti won ja ero olokada kan lole owo to to bi egberun metadinlogota (57K) niluu Nsukka
Igba ti awon olopaa yoo bere si ni tu inu aso eku won wo, ni won ba tun ba igbo lapo won.
Gege bi asa ile adulawo, ti eegun ba pidan tan, o ye o pada si igbale ni. Sugbon nipa ti awon eleegun ti owo te ni Nsukka, tesan awon olopa ni won pada si.

0 comments:
Post a Comment