Odun erofo to maa n waye niluu Boryeong to wa ni orileede South Korea
ti di gbajugbaja ti awon eniyan maa wa pewo bi iran lati awon orileede
agbaye.
Gege bi iwadii se fi ye wa, odun 1998 ni won bere odun erofo. Eleyii si waye lati sami bi won se se awari ohun alumooni ninu erofo kan to wa leba ilu Boryeong.
Odun erofo maa kun fun ijakadi, fifi erofo dara tabi fi se ise ona sara (body painting), bakan naa ni awon eniyan maa lo anfaani naa lati fi ya foto lorisirisi.
Odun yii ko ni i se pelu orisa kankan, odun ariya, idaraya ati imura-eni-ninu-dun lasan ni.
Igba to di wi pe odun naa bureke, ni awon agbateru odun naa bere si ni pe awon olorin lati lu fun ogoro awon eniyan ti won wa darapo lati kopa sodun erofo niluu Boryeong.

0 comments:
Post a Comment