Smiley face

Tani Oko Tuntun Funke Akindele (Jenifa)?


Ati igba ti fiimu Jenifa ti dobe fun Funke Akindele ni irawo osere naa ti pinnu lati teba ti awon ise to ba niise pelu 'Jenifa'. Aworan yii lo jewo ninu apa keji ere onise ti won pe akole re ni "Jenifa Diary" eleyii ti ko ni pe de oju iworan yin.



Ninu ere onise yii ni Falz ti n soko Jenifa, igbeyawo alarirnrin naa si dun.

Olorun nikan lo le fun eda ni idunnu ayo to kun. Ti emi ba si wa, ireti o sonu. Edua oke ni agbara lati so egan dogo. Mo si gbagbo wi pe laipe iyanu yoo sele.

E ku ikale!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment