Matilda Quaye |
Bi eniyan ba wo ibaradi omo naa lati iwaju, n se lo dabi ere kinsuwe ti won gbe kale ti won on bo bi Oosa. Bi eniyan ba wa yi si owo eyin lati wo ise iyanu ti Oluwa se, a fi bi oke olumo ti mbe l'Egba Alake. Awon kan lo dabi igba ti won ba di aso okirika kale. Apatapaara ogiri alapa ti ko le jabo laelae.
Yeepa! Iru ibadi wo leyii?
O le kakaraka lowo bi apo sanmonti [Olayemi, so ti fowo kan ri ni?]. Bee lo ranju kale fofoofo bi eja Sabalo ti won ta niluu Ilorin Afonja. Bi eniyan ba deju sile, e tun sakiyesi wi pe idi naa sakula bi maapu agbaye.
E ti e gbo na, ki lo kan mi pelu idi onidi na?
0 comments:
Post a Comment