Smiley face

Enikan Pataki Ti E Gbodo Mo Ki Odun Yii To Pari Ni Yii

Leta isale yii ni mo rigba lowo Ogbeni Kayode A. ti won gbe ni Ketu to wa ni Ipinle Eko.
Sugbon ki n to tesiwaju, gege bi oniroyin, mo sakiyesi wi pe lara nnkan to so ile Naijeria loruko buruku laaarin awon orileede agbaye ko ju nipa awon iroyin to n jade lati ile wa lo.


Kii se gbogbo awon omo ilu ti a mo si Niger Area tele ni oniro, gbogbo wa si ko ni onijibiti, sugbon pupo ninu awon oniroyin wa kii fe so nipa awon eniyan ti won ba n sise rere ayafi awon onise dudu lati le fi ta iwe iroyin won.

Mo je enikan to nife ilu mi, Nigeria. Ilu awon eniyan rere ati awon olopolo pipe eda.
Idi pataki si ni yii ti mo fi pinnu lati maa se igbelaruge fun awon olotito eniyan ti won lo opolo tabi ebun ti Olorun oba fun won ni ona ododo.

Mo pinnu lati se awon nnkan wonyii lai wo eya, esin, tabi ibi ti eni naa ti wa- Hausa, Yoruba abi Ibo.
Idi ni yii ti mo fi se afihan Alfa Salami ni awon akoko kan seyin gege bi okan ninu awon Alfa onimo nla ti Olorun n gbo adura won lati ran awon eniyan lowo.

Agbara gbigba adura ti Olorun fun Alfa Salami jo awon eniyan mimo loju pupo eleyii to mu won pawopo de ni lawani "Sheu Aseyori". Ori mi wu lojo ti won gbe Alfa Salami soke. A se lotito ni wi pe ile aye ni eniyan o ti bere si ni jere ise owo re ko to lo sorun alukiyamo.

Sugbon leta ti mo rigba tun jo mi loju, sebi eti to ba gbo alo di dandan ko gbo abo re. Leta naa ni yii:

"Olayemi Oniroyin, mi o mo bi mo se le dupe to lowo yin, sugbon Olorun oba nikan ni eni ti o san yin lesan ire. Mo dupe wi pe mo se alabapade Alfa Salami lati ori web site yin. Igba akoko ti e so nipa won, mi o tile koko kobi-ara si iroyin naa.

Sebi orisirisi iriri ti eniyan ti ri nipa awon oniro eniyan ti won fi oruko Olorun gba awon eniyan loju lo faa.
Sugbon ti Alfa Salami yato, eniyan Olorun ni won looto.

Bi won tile se koko n ba mi soro lori foonu mu inu mi dun pupo. Won fun mi ni ireti ninu Oluwa, won si fi n damiloju wi pe ko si isoro eda kan to koja ohun ti Oba Allah le segun re. Nipa agbara adua, ohun gbogbo ni sise.
Awon isoro kan ni mo n koju nipa ise mi eleyii ti mo lilo agbara Olorun. Mo pinnu lati gbiyanju Alfa Salam Sheu Aseyori, Olorun si ti ara won gbo adura mi.




Mo tun ni ore kan ti baba re ni aisan kan ti won pe ni stroke. Apa kan ati ese kan baba naa ti doku patapata. Mo salaye Alfa Salami fun ore mi naa. Si iyalenu mi, baba naa ti n pada rin bayii bi eni wi pe ko saisan ri. 


Mo wa lati wa so fun yin wi pe, lotito, olododo eniyan ni Alfa Salami. Eniyan ko si ni ba won pade ko kabamo laelae. Mo ko leta mi yii lati fi emi imoore han. Inu mi yoo si dun ti e ba le gbe leta naa sori afefe. E seun.
Kayode A
Ketu, Lagos."

Emi o mo ohun ti e n la koja, abi e tile ni ibeere kan lokan, e si tun le pe won lati ki won fun awon ise takuntakun ti won se; sebi yinniyinni keni tun le se mi-in ni Yoruba wi. Nomba yii ni e fi pe Alfa Salami:

0706 586 5035, 0811 328 0526


Ori email yii le o fi ko leta si mi pada nipa iriri yin lati odo Alfa Salami, ti emi o si pada gbe sori ayelujara:

Olayemi Oniroyin Agbaye, eran meta pere lemi o ni ba won pa laye n bi:
Emi o ni pasan
Emi o ni pofo
Emi o si ni ba won padanu nigbeyin aye mi.
E ku ikale.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment