Ese ko gbero lojo Satide to koja yii niluu Ilesa nibi ti tonile talejo
ti gbe pejo lati sodun Iwude Ijesa laafin Owa Obokun Adimula ti ile
Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran. Gege bi a se gbo, ayeye odun
Iwude Ijesa yii lo maa n fun awon omo Ijesa lanfaani lati foju kan oba
won laafin fun ikini odun eleyii ti ori ade naa yoo si ma sure fun
gbogbo omilegbe ero ti won ba wa yo ayo odun naa.
Eyi nikan ko, oba naa yoo tun ni anfaani lati se abewo si awon ibudo isembaye kaakiri tibu-toro ilu ilesa gege bi asiwaju asa ati ise ilu naa. Bakan naa ni awon oba to wa ni gbogbo igberiko pata ni Owa Obokun yoo yoju si eleyii to je okan pataki lara ayeye Iwude Ijesa.
Ayeye to ti bere lati ojo Eti ni won fenu re kole lojo Abameta pelu orisiirisii ere idaraya bi ayo tita, ijo ati orin ibile, afihan awon ohun isembaye ati ojulowo aso ile Yoruba. Lara awon alejo pataki ti won pejo saafin Owa Obokun ni gomina ipinle Osun, ogbeni Aregbesola, ati oga olopaa ile Naijiria nigba kan ri, Ogbeni Mike Okiro.

0 comments:
Post a Comment