Iroyin Owuro |
Olayemi Oniroyin, ti mo ba ni ina n jo lori omi, e ma ba mi jiyan rara, eru ni ke e beere fun. Iroyin Owuro ose yii tun gba ona ara mi yo pelu ise iwadii iroyin to fakiki. Ninu Iroyin Owuro ose yii, e ni anfaani lati mo ohun ti e ko mo tele nipa Gbenga Adeboye Abefe Jengbetiele.
Bakan naa ni alaye ati ona abayo nipa arun asekupani ti won pe ni Lassa Fever. Awon ohun to sele lagbo amuludun pata le e rika ninu Iroyin Owuro ose yii.
E gbiyanju kee bere lowo fendo yin, ogorun naira (N100) pere mi. E seun.
E gbiyanju kee bere lowo fendo yin, ogorun naira (N100) pere mi. E seun.
0 comments:
Post a Comment