DJ Abass |
Ti eniyan ba n gbe niluu London ti o ba mo DJ Abass (Abass Tijani) bi igba eniyan n gbe ni Africa ti mo DJ Jimmy Jatt ni. Ogbontarigi alariya ti n dana orin fun ni jo, erujeje onise opolo ti n pate orin dani laraya lode ariya, irumole ti won pebo lojo idunnu, oni ni ojo ibi re.
Abass omo Tijani lo sojo ibi ni Olayemi Oniroyin fi wa fope fun Oluwa Oba mimo, fun idasi ati ore ofee lati oke wa.
Abass omo Tijani lo sojo ibi ni Olayemi Oniroyin fi wa fope fun Oluwa Oba mimo, fun idasi ati ore ofee lati oke wa.
Mo gbadura wi pe, ki Edumare se aleekun ore, ayo ati alaafia fun-un.
#HappyBirthday
0 comments:
Post a Comment