Solomon Arase |
O ni ayewo yii ni yoo je ki awon mo awon olopaa to pegede yato si awon ti won yo ogun oloro mu nikoro ti won si n ba ile ise olopaa ile yii loju je nipa asilo ohun ija.
Oro yii ni Ogbeni Arese so niluu Abuja nigba to n se ifilole awon ero ayewo naa lojo kefa osu kerin odun yii [06-04-16].
Arase se alayii wi pe, eto yii ko wa fun awon olopaa to wa lenu ise nikan, eleyii yoo wa fun awon to ba fe gba ise olopaa bakan naa. Ayewo yii ni won yoo ma se nipa gbigba ito awon olopaa eleyii ti won yoo gbe sinu ero ayewo naa lati mo boya won lo ogun oloro tabi beeko.
0 comments:
Post a Comment