Smiley face

Mama Bukola Akinade (Sewele Jesu) ti lo sun ninu Oluwa

Sebi awon Yoruba loni, orisa bi iya ko si laye. N sebi iya ko si le dabi yeye to bi ni lomo.

Olubukola Akinade ti gbogbo eniyan mo si Sewele Jesu ti kede ipapoda iya re.

Atejade omobirin naa ni yii:

"WURA mi ti womi! She left unannounced, dis night, May26th, who can replace her in my life,? Lord,comfort my soul,whaoooo, just like that, Lord, I rely on U."

Ki Edumare te mama naa si afefe rere!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment