Gegeg bi alaye ti a gbo, ise oju ona ti won se lo ni agbegbe epe niilo fun ki won wo awon ibi kan, eleyii ti won sin oku obirin kan si.
Idi ni yii ti won fi wu oku naa jade. igba ti won yoo wu jade, bi won se gbe oku naa sinu koto lati bi odun kerinla seyin (14) naa ni won ba nibe. Oku na ko jera, ko si baje. #Iyanu
0 comments:
Post a Comment