#AyeOlabisiK29
Ẹ le ka itan igbesi aye Olabisi K to ti jade tẹlẹ NIBI ki ẹ to tesiwaju lati ka eleyii ki itan naa le yeyin daada
Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ
Haolat Precious Bukky: Awa ololufe yin tin binu gan ni fun pipe ti enpe ki eto ko leta naa ranse siwa. Tori oro na kofe yewa mon bai yii o.
Prince Asabi Oluyinka Johnson: Mo ro pe itan aroso lasan ni e sa je kari eko ko ni ipari itan
Lexyman Smally: igba wo ni a o gbo iyoku oro yii bayi,emi o feran kia a maa foju ara eni sona oooooooooooooooooooo
Adegboyega Siji: Oloooto ko ni i ku sipo ika. Bi o tile je pe kile to posika,ohun rere le ti baje,sibe,ododo ni yoo leke.A n foju sona fun leta to ku.
Adeboye Morenikeji: Inu mi dun si atejade yii sugbon bawo ni iba ti dun to ko je wipe gbogbo awa ti a nba oro yii bo lati ibere pepe ni a ni anfani lati gbo ipari re, amoo pipe ti oro yii pe ti mu wa so opolopo awon ayanfe nu ninu ilu yii(Yoruba dun).Mowa nfi asiko yii ro olootu pelu awon agbateru re pe ; ki ejowo gbe akanse eto kan kale ni waransesa (ti o yio jemo bi ere idaraya tabi omiran) lati lefi pe awon ayanfe wa ti won ti sakolo padabo wa sile.

Olootu ,ema gbagbe wipe afúnntó ni aje fun yin ninu ilu yoruba dun yio .Asunji o,odaarooooo
Aríyíbí Qósìm Adésolá: E kú làákàyè.
Gbemitosin Oje-Olubowale: E ya ma pe rara o
Udeh Gloria: Atejade yii ti ma n peju ki o to jade.sugbon adura mi nipe ki olodumare ki o ran yin lowo amin.
Gbemitosin Oje-Olubowale: Gloria,i cant write yoruba d way u've written it..U've really tried.
Udeh Gloria: Ore mi julianah,o ba gbiyanju die tori ko si ohun ti ko se se tabi ti kole sele.gbiyanju re wo!
Odunaiya Olubolade Victor: Olootu mo fe ko ye yin pe eni to ba maa je eyin inu apataa koni wo enu aake,ohun yio wu ko le sele eyin esaa matesiwaju,afe itan to ku ni waransesa.
Olaitan Opeyemi Olootu eku ise opolo,amoran temi fun yin ni wipe ki e ma se fi igba kan bokan ninu,OLOHUN Atun bo maa fun yin se asi tun maa ran yin lowo.
Wunmi Wale: E ma foju wa sona
Afolabi Joseph Olanrewaju Ti mi ko ba ni yaju, mi o ba beere omo ilu wo ni Udeh Gloria se?
Gbemitosin Oje-Olubowale: 10x my fwend,i will b trying.
Adepoju Busayomi Rofiat: AFI KI edumare se anu awa obirin lowo awon oga ile ise gbogbo. olootu ejo e ma je ko pe lati pari e.
Ẹ tẹsiwaju ninu itan igbesi aye Olabisi K NIBI
0 comments:
Post a Comment