Smiley face

Ibiwunmi Abimbola Taiwo: Ọmọ ọlọjọ-ibi fọpẹ f'Oluwa

Ẹni ọdun ba laye, ẹ pe ko sọpe. Ẹ ni Edumare ba dasi, ẹ pe ko fiyin f'oluwa. Ore ọfẹ lasan lẹda rigba, kosi ẹni to pe tan niwaju Oluwa ọba.
Ibiwunmi Abimbola Taiwo
Arabirin Ibiwunmi Abimbola Taiwo lo se ọjọ ibi lonii, ki lo wa buru taa ba ba iru won dupẹ lọwọ Ọba mimo? Olori Modupẹtemi ti samọdun gbogbo wa la n yọ faya rere lọọdẹ ọkọ.

Olori Modupetemi gbayi pupo!
Arabirin  Ibiwunmi, igba ile rẹ ko ni fọ, awo ile rẹ ko ni faya, ire owo, ire ọmọ, ayọ, idunnu, igbega ko ni tan lọọdẹ rẹ. Amin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment