Smiley face

Awon ara ti Mercy Aigbe tun da ni yii

 
Diẹ lara awon foto lati ibudo ere eleyii ti Mercy Aigbe n se lowo ni yii.  Pelu iru awon aworan to jade yii, awon kan ni oseese ko jẹ isẹ nabi ni fiimu naa yoo da le lori.

Sugbon sa, se okunrin ni ọlọyan nla oke yii ni tabi obirin?
Afeez owo seriki olopolo pelu Mecy
 
Mercy Aigbe ni yii pelu Cossy Orjiakor, okan pataki ninu awon ti n se fiimu onihoho ile Naijiria. Igba akọkọ kọ ni yii ti omobirin naa yooma n patẹ oyan rẹ sita. Ẹ tun le ka nipa Cossy Orjiakor NIBI, NIBI, NIBI, NIBI, NIBI, NIBINIBI, NIBI ati NIBI




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment