Funke Akindele tí padà wá dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ fún ìfẹ́ àti àdúrà wọn nígbà ìṣòro.
Funke Akindele lágbo wí pé ó pàdánù oyún ibeji to ni lẹ́yìn tí àwọn ènìyàn tí ń bá dúpẹ́ wí pé osere náà tí finu soyún.
Ọwọ́ to nù omijé ẹni nù nígbà ìṣòro, ó ju ẹgbàá ọwọ́ tí ń yẹnisi lọ ní àkókò adùn.
Kaakiri agbaye ni àwọn ènìyàn tí ń ṣe àdúrà fún un, bakan naa ni won mu lọ́kàn lè wí pé Olúwa yóò ṣe èyí tó dara.
"E ṣeun mo dúpẹ́ fún aduroti yin, " báyìí ni Jenifa ṣe ń kí àwọn olólùfẹ́ rẹ lórí ayelujara.
0 comments:
Post a Comment