Smiley face

Ìfọ̀rọ́wérọ̀ láàárín @DeleMomodu àti @Atiku

Dele Momodu: Púpọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà ni wọ́n wo Atiku gẹ́gẹ́ bí ọkàn lára  àwọn olóṣèlú jẹgúdújerá?

Atiku: Mo ti sọ̀ tẹ́lẹ̀ wí pé bí ẹnikẹ́ni bá ní àṣírí ìwà ajẹbanu tí mo wù kí wón jáde. Kété ti mo sọ̀rọ̀ yìí ni wón ti lo n wa àṣìṣe tí wó  fi lè tako mi. Ṣùgbọ́n títí di àkókò yìí, mi o ri ẹnikẹ́ni pé mi lẹ́jọ́. Èyí túmọ̀ sí wí pé wọ́n ko  ri ẹbọ kankan lẹ́rù mi.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment