" Tí mo bá díje ipò aare pẹ̀lú Buhari lọ́tẹ̀yí, ó dájú wí pé màá fẹ̀yìn rẹ̀ janlẹ̀. Ìdí ni wí pé, Buhari ti n pàdánù ìfẹ́ tí àwọn ènìyàn ní sì. Ìlú ò rọgbọ, àwọn ènìyàn kan ń mú u mọ́ra lasan ni. Àìmọye àwọn ènìyàn ni ara ń ni ṣùgbọ́n tí wọn pa á móra. Ìyá ń jẹ àwọn ọ̀dọ́, wọn tilẹ̀ ti bere si ni ta wọn lẹ́rú báyìí nílùú òkèèrè." - Atiku
Die lara iforowero Atiku Abubakar àti Agbaoje oniroyin, Dele Momodu
0 comments:
Post a Comment