Smiley face

Bí ẹ ṣe lè ṣe ìtọ́jú Ibà (Thyphoid Fever) pẹ̀lú tewe tegbo

Láti ṣe ìtọ́jú ibà (Thyphoid Fever) . Àwọn èròjà ìsàlẹ̀ yìí là má wá :

Èwe gurofa
Èwe ibepe
Èwe dongoyaro
Epo igi mango
Èwe ọsan wẹ́wẹ́
Ọsan wẹ́wẹ́ méje

Ìpèsè: A má gé gbogbo èròjà yìí sí wẹ́wẹ́. A wá ṣe lórí iná pelu omi bí lita mẹ́rin fún ogójì ìṣẹ́jú.

Lílò: ìlàjì koopu ni ẹni náà yóò má mú lojoojumo.

Àkíyèsí: Joojumọ ni ẹ má gbé àgbo yìí ka orí iná. Eléyìí yóò mú tọjọ, ìṣe rẹ yóò sì péye.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment