Smiley face

Ohun tí a lè ṣe tí obìnrin bá ní kòkòrò ojú ara ní yìí

Láti ṣe ìwòsàn fún obìnrin tó bá ní kòkòrò ojú ara, àwọn èròjà yìí là má lo.

Èwe ewuro
Èwe efirin

A má gbo èwe méjèèjì yìí papọ. Lẹ́yìn èyí ni a wá fi gbó ojú ara.

Bákan náà ni a lè mú omi ti a fún jáde lára èwe méjèèjì yìí lẹmeta lojumo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment