Tí ẹ̀jẹ̀ kò bá dá lara obìnrin lẹ́yìn to bá bímọ tán. Ohun tí a ṣe láti ṣe ìwòsàn fún ní kíákíá ni yìí; kò tó pàdánù ẹ̀jẹ̀ ara rẹ lọpọlọpọ.
Láti ṣe ìwòsàn, igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ là má gé. Tí a bá gé, a má fún omi ara igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ náà sinu kọọpu fún obìnrin náà láti mú.
Ní agbára Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ náà yóò dawọduro lesekese.
Yàtò sì eléyìí, a lè tú ìgò coke coca cola bí mẹ́jọ sínú baafu kan kí obìnrin náà sì jókòó sínú rẹ. Eléyìí náà le mú ẹ̀jẹ̀ náà dawọduro.
0 comments:
Post a Comment