Smiley face

Ìtàn Olajumoke arẹwà obìnrin (pt7)

OLAJUMOKE APA KEJE:

Bi won se nlo ni Oriola ń yi lo gbirigidi ńiwájú Olajumoke tele bẹẹni Abami naa tele wọn.

Wọn rin titi won fi de'le Oriola ṣùgbọ́n Olajumoke ko ma dake ẹkún. 

Nigba tiwon wole tan niwon fi yara Olajumoke han an. Nígbà tí ile su tan, gbogbo awon iwin ati anjonu ati onírúurú awon emi abami ni wọn wa ki Oriola nítorí oloye nla ni láàrín wọn.

Won beere ere ati ariya, oríṣiríṣi idan níwọ̀n pa ninu aginju nla náà.

Nígbà tí o ya won mu Olajumoke sáàárín pelu oko re, won tagbo yí wọn ká. Oriola bèrè sí í jo, bó se n fo soke lo tun nyi nile gbirigidi.

Ṣùgbọ́n gbogbo ere yii lo je iyalenu fun un, nigbat'oya won paaro aso lara Olajumoke won fi ewe boo lara, igbayi lo to mo pe ouun ti jin soofin awon iwin.

Won fa irun ori re won si fi ewe we gele fun... e maa bami kalo...

Orísun: Emmanuel Oluwafemi Felix

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment