Olaniyi Afonja, Sanyeri, ti fi gbogbo awon ololufe re lokan bale nipa sinima tuntun re eleyii to pe ni Omo Alhaja. Aimoye awon ose...
Read More
Home / Amuludun
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Toyin Aimakhu fabinu yo niluu Abuja: Oro oko lo fa gobe
Bi eniyan ni oun ko ni soogun ika, eni ti yoo jewo ko ni je. Alaye yii ni a le fi we bi awon oniroyin kan se kan Toyin Aimakhun leewo...
Read More
Lara ohun to wa ninu ile Wasiu Ayinde Marshal ni yii
Awon Yoruba so wi pe, ogongo loba eye; ti a ba si n so lagbo fuji, oba ni Wasiu Ayinde omo Anifowose je. Se ki n se wi pe owe n...
Read More
Gbajumo Osere Ibrahim Chatta gbe iyawo keta
Kehinde Oladeji -Won ni tori obinrin naa loyun fun ni o se fe e Bi aheso ni oro naa se koko ru sita ni ose meji seyin wipe gba...
Read More
Kola Olootu lori Dele Thomas African FM Radio, Houston Texas
Dele Thomas ati Kola Olootu Otunba Kola Olootu, Baasoro Ile Yoruba, tun ti pade sile Amerika, eleyii ti n se igbakeji re laaarin osu ...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)