Smiley face
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Séríkí Amuludun of Yorubaland: Oga Bello ni won gbe fun

Séríkí Amuludun of Yorubaland: Oga Bello ni won gbe fun

Wọn ti fi Alhaji Adébáyò Salami tí gbogbo ènìyàn mo sì Oga Bello jẹ Sariki Amuludun of Yorubaland. Àwọn ẹgbẹ́ kan tí ń jẹ Ilorin Emerate Dec...
Read More
Davido pahùn dà, "Mr. Dele na my Daddy" : Ìjà parí láàárín ìdílé Adeleke ati Momodu

Davido pahùn dà, "Mr. Dele na my Daddy" : Ìjà parí láàárín ìdílé Adeleke ati Momodu

Ìkùnsínú to bẹ sile ni awon akoko kan seyin láàárín ìdílé Adedeji Adeleke ati ìdílé Dele Momodu lọ ti pari bayii. Wàhálà  yìí ló bere nígbà...
Read More
"Pasuma @ 50 to n se bi omo 15" - Talo sọ bẹẹ? Wàhálà Paso àti Malaika sì ń gbóná

"Pasuma @ 50 to n se bi omo 15" - Talo sọ bẹẹ? Wàhálà Paso àti Malaika sì ń gbóná

Bí ó tilè jé wí pé Sulaimon Alao Malaika kò ju ọmọ ọdún merinlelogoji (44)lọ, ó fi àgbà hàn Pasuma tó jẹ́ ọmọ  àádọ́ta ọdún (50), nipa ìwà o...
Read More