Apero awọn sẹnatọ: Orukọ Ọba Odulana gbọdọ di manigbagbe Olayemi Oniroyin 1/31/2016 04:20:00 pm Add Comment Edit Ọba Samuel Odulana Ile igbimọ aṣofin Abuja, ti rọ ijọba apapọ lati sọ orukọ Ọba Samuel Odulana to doloogbe di manigbagbe ni oril... Read More
Awon foto Ooni Ojaja laafin Awujale Ijebu-Ode Olayemi Oniroyin 1/30/2016 01:06:00 pm Add Comment Edit Ooni Adeyeye wo Ijebu Ode lojo Eti to koja yii ( 29/01/16) lati ba Awujale lalejo Read More
Tinubu wo ilu Ibadan nile Oluyole Olayemi Oniroyin 1/24/2016 11:11:00 pm Add Comment Edit Oloye Bola Tinubu wo ilu Ibadan lati wa ba idile Oba Samuel Odulana to waja kedun. Sugbon ile ijoba ipinle Oyo lo koko gba lo lati se... Read More
Wahala ti be sile leyin iku Olubadan Olayemi Oniroyin 1/24/2016 02:36:00 pm Add Comment Edit Seriki n du ipo oba Olubadan Gbogbo aye n ki Balogun Olubadan ku oriire Gomna ko ti mo ohun ti yoo se lori wahala naa Aafin O... Read More
Omowe Adesina fi geesi ko ede Yoruba pombele Olayemi Oniroyin 1/22/2016 04:06:00 pm Add Comment Edit Omowe Oluwole Adesina Tiwa-n-tiwa takisa taatan. Omowe Wole Adesina ti se agbekale iwe eko ede Yoruba pelu ede geesi to pegede fun ... Read More