Reuben Abati To je oludamoran nipa Eto Iroyin fun ijoba apapo ti jeri wi pe
iro patapata gbaa ni iroyin to so wi pe Aare Goodluck lo si ilu Kenya pelu Baalu Meje. Gege bi oro re, oni isokuso ni omobirin ile Kenya n so lori afefe wi pe Aare Goodluck to je Aare mekunnu fo lo si ile Kenya pelu orisii baalu meje(7).Reuben Abati so wi pe baalu kan pere ni oga oun gbe lo si ile Kenya. ati wi pe eni to ba ni eri to giriki ko se afiihan re fun gbogbo aye. #Lobatan
0 comments:
Post a Comment