Smiley face

Omo Naija Ti Pa Iyawo Re Pelu Oyun Osu Mesan-an Si Ilu Amerika

Owo awon Olopa oloju ina ti te Babatope Owoseni ni East Orange, New Jersey ni ilu Amerika latari esun wi pe o seku pa iyawo re, Fatoumata Owoseni pelu oyun osu mesan-an.

Borogidi ni awon olopa ba oku iyawo re nile ninu ile ti oun ati oko re n gbe ti omobirin naa ko si le mira mo.

Iwadii awon olopa New Jersey fi ye wa wi pe n se ni Mr Tope fun iyawo re lorun pa mo inu ile.

>>>>
Ibeere mi ni wi pe iru ese wo ni iyawo re le se to fi le wu iru iwa bee? Ko maa lo je wi pe awon aye wa ni nidi oro yii, abi kini eyin ro? Abi ka so wi pe ibinu abisodi lo mu oko pa iyawo re ni?

Iwadii si n lo lowo, igbeyin oro gan-an la o mo talo jebi ati iru idajo wo loye fun ika eniyan.

Olayemi Oniroyin ni emi nje. Ilu Naija si ni emi n gbe. E ku odun!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment