To ba je wi pe a ki i ku laye, awon ara igbaani da? To ba je wi pe eni wa saye kii ronu, se awon ara atijo ko ba si wa lojude.
Oku olowo ni won se lodun kan, oku otose eniyan losu mefa, oku olomo laseesetan. Bi eni rere ba ku, aye ki i gbagbe won boro.
Oni ojo karun-un osu kesan-an odun 2016 lo pe odun meje ti Abdul-Ganiyu Oyesola Fawehinmi ti lo ba oba Allah loke.
Sebi titi laelae laa ma se iranti olododo.
Sun-un re, ogboju loya ti n fese so asebaje nigbaaya nita gbangba.
0 comments:
Post a Comment