Goolu gidi loruka igbeyawo Funke Akindele Olayemi Oniroyin 9/05/2016 05:01:00 pm Add Comment Edit Leyin igbeyawo bonkele ti Funke Akindele se, osere onitiata naa ti pada se afihan oruko igbeyawo re eleyii ti awon kan pe ni ojulowo goo... Read More
Toyin Aimakhu pe omo odun mejilelogbon lonii (32) Olayemi Oniroyin 9/05/2016 04:57:00 pm Add Comment Edit Toyin Aimakhu pe omo odun mejilelogbon lonii (32), ojo karun-un osu kesan-an odun 2016. #Igba odun odun kan ni. Ase Read More
Ayo abaratintin: Iyawo Akpororo bimo obinrin. Olayemi Oniroyin 8/31/2016 04:19:00 pm Add Comment Edit Oladeji Kehinde Ti won ba gesin ninu re lanaa o daju pe eniyan o ni kose Akoko idunu gbaa ni akoko yii je fun Akpororo àti Iyawo re, Jo... Read More
Fiimu tuntun Iyabo Ojo ti gori igba: BLACK VAL Olayemi Oniroyin 8/29/2016 12:35:00 am Add Comment Edit Awon Yoruba bo, won ni aileja nita baba mi ko de hin-in. Bi o tile je wi pe pupo awon ololufee Iyabo Ojo mo osere naa mo awon ise fiimu ... Read More
Awon nnkan ti e ko mo nipa oko tuntun Funke Akindele: JJC. Olayemi Oniroyin 8/29/2016 12:14:00 am Add Comment Edit Eyi ni die alaye nipa oko tuntun ti Funke Akindele n fe bayii. Oruko okunrin naa ni Abdul Rasheed Bello ti gbogbo eniyan mo si JJC, ... Read More