Ogede omoge meje ni mo n je, Floyd Mayweaher lo so bee Olayemi Oniroyin 9/13/2017 04:54:00 pm Add Comment Edit "Awon omoge meje ni mo n je ogede agbagba won papo leekan naa." Floyd Mayweaher, afeseku bi ojo lo so bee. Ninu alaye re to t... Read More
Sangbafọ! Gbajumo oserebirin ile Naijiria ti sin ọmọ rẹ kan soso Olayemi Oniroyin 9/07/2017 10:59:00 pm Add Comment Edit Ibanujẹ nla ni ki obi fi ọwọ re sin omo rẹ tobi. Pelu ẹdun okan nla ni mo fi n kede fun yii wi pe, Eucharia Anunobi, oserebirin elede geesi... Read More
Kosi oyun nikun Funke Akindele - oko re lo so bee Olayemi Oniroyin 7/01/2017 09:19:00 am Add Comment Edit Ogbeni Abdul Rasheed Bello ti inagije re n je JJC Skillz ti o je oko FunkeAkindele ti salaye wi pe, kosi oyun nikun osere naa bayii. ... Read More
Lola Alao soro nipa awon obirin ti won dalemosu Olayemi Oniroyin 7/01/2017 08:45:00 am Add Comment Edit Lola Alao Gbajugbaja onserebirin ile Naijiria, Lola Alao ti salaye wi pe, gbogbo obirin ti won ba dale mosu, asise ni won se nigba t... Read More
Saheed Osupa ti se ifilole African Delight TV Olayemi Oniroyin 6/30/2017 08:43:00 pm Add Comment Edit Saheed Osupa Oba Orin Saheed Osupa ti kede ifilole telifisan re eleyii to pe ni African Delight TV . TV yii je tori ayekujara eleyii... Read More