Owolabi Ajasa tí di agunbaniro Olayemi Oniroyin 1/25/2018 10:56:00 pm Add Comment Edit Kosi ìgbà tá daso taa r ilẹ fi wọ Read More
Ipadabo Jelili Oniso yóò lágbára - Femi Adebayo ṣe ìlérí Olayemi Oniroyin 1/25/2018 10:52:00 pm Add Comment Edit Femi Adebayo tí fi àwọn olólùfẹ́ rẹ lọ́kàn balẹ wí pé, ipadabo Jelili Oniso ọ̀tẹ̀ yìí yóò lágbára gan-an ni Read More
Eniola Ajao dẹni àjífìlùkì Olayemi Oniroyin 1/22/2018 01:24:00 am Add Comment Edit O wu Edua Òkè lọ gbé ògo ńlá f'ọkin. Ọkin alarambara aṣọ oge. Ó wu Edumare lo sọ Eniola dẹni àjífìlùkì. HAPPY Birthday 21/01/ 18 &#... Read More
O dabi ẹni wí pé ara ti tu Davido: Ó ti bèrè pàlàpálá Olayemi Oniroyin 1/17/2018 05:30:00 am Add Comment Edit Ko ma lọ je ogún oloro ni wọn tún dá sofun. Bẹ́ẹ̀ ọtí àmupara lo ṣekú pa ọkàn nínú àwọn ọrẹ Davido lojosi. Mí ó fé gbọ sitori kankan mo wí p... Read More
Àwọn ènìyàn tí bere ibanikedun ikú màmá Yomi Fabiyi Olayemi Oniroyin 1/13/2018 11:10:00 pm Add Comment Edit Káàkiri agbo Amuludun ni àwọn ènìyàn tí ń bá Ogbeni Yomi Fabiyi kẹ́dùn pelu bo se pàdánù ìyá rẹ. Kí Olúwa tẹ màmá sì afẹ́fẹ́ rere. Àmì Read More