Igbeyawo Ooni Adeyeye Ogunwusi larinrin niluu Benin Olayemi Oniroyin 3/12/2016 07:51:00 pm Add Comment Edit Won ti fa Olori Wuraola Otiti le Ooni Ile Ife , Oba Adeyeye Ogunwusi lowo lonii niluu Benin. Bi o tile je wi pe baba kosi nibi eto igbeya... Read More
Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga? Olayemi Oniroyin 2/28/2016 09:03:00 pm Add Comment Edit *Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewu... Read More
Awon igbimo Olubadan foju Seriki gbole ni kootu Olayemi Oniroyin 2/27/2016 10:51:00 pm Add Comment Edit Saliu Akanmu Adetunji *Won ti dajo iwuye Adetunji gege bi Olubadan tuntun Gege bi oro awon Yoruba to wi pe, ti oba kan ko ba... Read More
Seriki ti gbe Ajimobi lo sile ejo latari oye Olubadan Olayemi Oniroyin 2/14/2016 04:00:00 pm Add Comment Edit *O tun fesun kan awon omo igbimo Olubadan ati adajo agba * “Enikeni ko to si ipo Olubadan ayafi Oyediji” Idile Seriki Gomina... Read More
Olubadan pada wole sun n’Igbo Elerin Olayemi Oniroyin 2/14/2016 10:46:00 am Add Comment Edit *Ajimobo, Ambode, Aregbe ati Amosun bu ola fun Oba Odulana *Gbogbo oja ni won tipa lojo ti won sin Olubadan *“Alailabawon oba il... Read More