Saheed Osupa kọrin níbi ọdún Isese eléyìí to wáyé loke MAPO, Ibadan, 21-01-2018. Àkòrí ọdún náà ni IGBARUMOLE eléyìí tí Erelu Amope Olorisha...
Read More
Home / Asa Yoruba
Showing posts with label Asa Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Asa Yoruba. Show all posts

OJULOWO ỌMỌ YORÙBÁ: Ẹ pàdé Isaac Owolabi pelu Morenike
"Ẹ kú u dééde àsìkò yìí o, A sì kú iṣẹ́ àtàárọ̀, Àlejò mi àkọ́kọ́ lórí OJULOWO ỌMỌ YORÙBÁ ti yóò wayé lọjọ Àbámẹ́ta lori àtẹ Yoruba Dun...
Read More

Saheed Osupa kọrin fún àwọn Igbarumole
Saheed Osupa kọrin níbi ọdún Isese eléyìí to wáyé loke MAPO, Ibadan, 21-01-2018. Àkòrí ọdún náà ni IGBARUMOLE eléyìí tí Erelu Amope Olorisha...
Read More
Yeye Agbasaga Morenike Toriola: OJÚLÓWÓ ỌMỌ YORÙBÁ
Ẹ kú asiko yii ẹyin ènìyàn wá, eleyii ni lati fi tó yín létí wí pé, abala eto tuntun yóò gorí atẹ Yorùbá Dùn eléyìí tí a n pè ní OJÚLÓWÓ ỌMỌ...
Read More

Oríkì Ilu Ede: Ó ti pe ọdún mẹ́wàá báyìí tí Ọba Muniru Adesola tí gorí ìtẹ́
Oríkì Ede Ede màpó arógun, Iyako agbo Èyin Ọmọ ají lala ọsọ Ọmọ ají sọsọ Ọmọ ají f'ọjọ́ gbogbo dára bí egbin, Ede ọmọ elepo rédé, ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)