Saheed Osupa: Mr. Biggy Olayemi Oniroyin 6/08/2016 10:18:00 am Add Comment Edit Ninu ero mi, mo ro wi pe o dara ju ki Saheed Osupa ma wọ iru awon asọ bayii lọpọ igba ju awon asọ ibilẹ lọ. Read More
Kim, Kanye ati omo won yọ bi ọjọ Olayemi Oniroyin 6/06/2016 05:07:00 pm Add Comment Edit Omoge onibadi olokiki ilu Amerika, Kim, tun gbeyo bi ojo pelu awon ebi rẹ Read More
Lara awon aso oge igbalode naa ni Olayemi Oniroyin 6/06/2016 04:39:00 pm 1 Comment Edit Se aso naa niyii? Read More
Omo Gomina Ajimobi wọsọ N1.4M lọ sariya Olayemi Oniroyin 6/03/2016 09:56:00 pm Add Comment Edit Okan ninu awon omobirin Gomina Ajimobi lo wose yii. Nigba ti awon eniyan yoo lọ wo iye owo aso naa lori igba, won ri wi pe, iye owo aso ... Read More
Baagi oge fun awon omoge asiko Olayemi Oniroyin 6/02/2016 11:11:00 pm Add Comment Edit Baagi yii ni mo ri lori Konga, mo si mo wi pe awon omoge asiko maa fe niru baagi yii lowo. Kosi ode ti eniyan ko le gbe wọ, ẹwa ara ... Read More