Aya Femi Gbajabiamila dira fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́ta ọdún Olayemi Oniroyin 5/28/2018 05:37:00 pm Add Comment Edit Adari ọmọ ẹgbẹ́ to pọ̀ jù lọ nílé ìgbìmọ̀ aṣojú sofin Abuja, Femi Gbaja ṣe ajọyọ pẹ̀lú aya rẹ, Yemisi Gbaja, pẹ̀lú bo se pe ẹni àádọ́ta ọdún... Read More
Ká mú tẹ̀gàn kúrò, Telu rẹwà lọkunrin Olayemi Oniroyin 5/27/2018 02:25:00 pm Add Comment Edit Kò sí ohun tó burú láti nawọ́ ìfẹ́ si àwọn ẹ̀yà to kú lórílẹ̀ Nàìjíríà 🇳🇬 , sebi ọkàn náà ni gbogbo wa. Ṣùgbọ́n gẹ́g... Read More
Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí Olayemi Oniroyin 5/17/2018 07:00:00 pm Add Comment Edit "Olólùfẹ́ mi, aya mi, Akankẹ mi, bí mo bá wà sílè ilé ayé nígbà igba, ìwọ kan náà lọ má jẹ aya mi. Àìmọye ìdùnnú lọ fún mi ti mi ò lé r... Read More
Oludasilẹ Facebook, Mark Zuckerberg pé ẹni ọdún mẹ́rinlelọgbon (34) lónìí Olayemi Oniroyin 5/17/2018 10:25:00 am Add Comment Edit Òní, 17/05/18, ni ọjọ́ ìbí oludasile Facebook, Mark Zuckerberg, eléyìí tí gbogbo wa njẹ àǹfààní rẹ lónìí. Kí n tó kí Mark fún ayẹyẹ ọjọ́ ì... Read More
Happy Birthday Oluwafunke Etti Olayemi Oniroyin 4/25/2018 12:37:00 pm Add Comment Edit Òní ni ọjọ́ ìbí osere òní tíátà, Funke Etti. Igba ọdún, ọdún kan ni. Àṣẹ Read More