Smiley face
Showing posts with label Ilera Loro. Show all posts
Showing posts with label Ilera Loro. Show all posts
Ewe ati egbo Yoruba: Ogun Lapalapa

Ewe ati egbo Yoruba: Ogun Lapalapa

Lapalapa kii se ohun to ye ka faye gba rara. Ti lapalapa ba wa jade si wa lara, ona abayo ni yii. E po ogidi oyin papo mo omi osan w...
Read More
Lara ise iyanu ti ogidi oyin se ni yii

Lara ise iyanu ti ogidi oyin se ni yii

Nnkan ibanuje nla ti oyun ba n wale lara obirin ni gbogbo igba. Awon ti iru nnkan bayii ba n se tabi obirin ti n ri nnkan osu re ninu oy...
Read More
Ewe ati egbo Yoruba: Ato okunrin ti ko pe oju osunwon

Ewe ati egbo Yoruba: Ato okunrin ti ko pe oju osunwon

Eroja: A ma wa ewe gurofa ati omi to loworo die. Ipase: A ma gbo ewe gurofa yii sinu omi to loworo ti a gbe kale. Lilo: E ma mu koop...
Read More
Ewe ati egbo Yoruba: Obirin ti inu run ni akoko nnkan osu re

Ewe ati egbo Yoruba: Obirin ti inu run ni akoko nnkan osu re

Ona abayo ni yii fun obirin ti n se nnkan osu ti inu ma n run. Ti o ba je wi pe inu rirun onidodo ni, ohun ti e ma se ni wi pe, e ma wa ...
Read More
Kini obirin le se ti nnkan osu re ko ba wa daada?

Kini obirin le se ti nnkan osu re ko ba wa daada?

Ti nnkan osu obirin ko ba wa daada gege bo ti ye ko ma wa, ona abayo ni yii. Ohun ti e ma wa ni ewe eti erin ti awon onigeesi n pe ...
Read More