Aye oba dun: Ooni Ojaja II foju ba Nottingham to Nottinghamshire (fidio) Olayemi Oniroyin 3/26/2017 07:33:00 am Add Comment Edit Orisun:Thamarzeen Kaka Read More
Won ti dajo ewon gbere fun ojowu obirin. E w gba ohun to se Olayemi Oniroyin 3/22/2017 01:17:00 pm Add Comment Edit Awon Yoruba bo, won ni ojowu obirin, bi ko pa ara re, afaimo ko ma pa oko re. Ki lo le mu obirin da acid si oko re loju? Ki lo le to bee? ... Read More
[Video] Nothing Hill Carnival 2016 niluu London Olayemi Oniroyin 8/30/2016 07:30:00 am Add Comment Edit Nothing Hill Carnival 2016 niluu London: die lara awon ariya ti n san nibe ni yii. 🎉 #goodtimes #nothinghillcarnival #jam... Read More
[Foto] Nothing Hill Carnival odun 2016 lekenka niluu London Olayemi Oniroyin 8/30/2016 07:00:00 am Add Comment Edit Awon Yoruba lonii odoodu laa rorogbo, odoodun la rawusa. Sebi todun ba ti dun laa romo obi lori ate. Nothing Hill Carnival 2016 tun ti w... Read More
Odun Tomato dun yungbayungba niluu Spain Olayemi Oniroyin 5/09/2016 05:41:00 pm Add Comment Edit Odun Tomato niluu Spain Gẹgẹ bi itan isẹdalẹ Yoruba se fi ye wa, ẹni ti won kọkọ kọla fun, ika ni won fi se fun-un. Igba to ya ni ila ... Read More